JOHANU 1:43-44

JOHANU 1:43-44 YCE

Ní ọjọ́ keji, bí Jesu ti fẹ́ máa lọ sí ilẹ̀ Galili, ó rí Filipi. Ó sọ fún un pé, “Máa tẹ̀lé mi.” Ará Bẹtisaida, ìlú Anderu ati ti Peteru, ni Filipi.

Àwọn Fídíò tó Jẹmọ́ ọ