AISAYA 1:19-20

AISAYA 1:19-20 YCE

Bí ẹ bá fẹ́, tí ẹ sì gbọ́ràn, ẹ óo jẹ ire ilẹ̀ náà. Ṣugbọn tí ẹ bá kọ̀, tí ẹ sì ṣoríkunkun; idà ni yóo run yín.” Bẹ́ẹ̀ ni OLUWA sọ.