ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 8:13

ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 8:13 YCE

Simoni náà gbàgbọ́, ó ṣe ìrìbọmi, ni ó bá fara mọ́ Filipi. Nígbà tí ó rí iṣẹ́ abàmì ati iṣẹ́ ìyanu ńlá tí ó ń ṣe, ẹnu yà á.