ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 3:22

ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 3:22 YCE

Mose ṣá ti sọ pé, ‘Oluwa Ọlọrun yín yóo gbé wolii kan bí èmi dìde láàrin àwọn arakunrin yín. Òun ni kí ẹ gbọ́ràn sí lẹ́nu ninu ohun gbogbo tí ó bá sọ fun yín.