KRONIKA KEJI 18:13

KRONIKA KEJI 18:13 YCE

Ṣugbọn Mikaya dáhùn pé, “Mo fi orúkọ OLUWA búra pé ohun tí Ọlọrun bá sọ fún mi pé kí n sọ ni n óo sọ.”