SAMUẸLI KINNI 18:4

SAMUẸLI KINNI 18:4 YCE

Ó bọ́ aṣọ tí ó wọ̀ fún Dafidi, ó sì kó ihamọra rẹ̀ pẹlu idà ati ọfà ati àmùrè rẹ̀ fún un.