1
Saamu 78:7
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Nígbà náà ni wọ́n ò fi ìgbẹ́kẹ̀lé wọn sínú Ọlọ́run wọn kò sì ní gbàgbé iṣẹ́ Ọlọ́run ṣùgbọ́n wọn ó pa àṣẹ rẹ̀ mọ́.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 78:7
2
Saamu 78:4
Àwa kì yóò pa wọ́n mọ́ kúrò lọ́dọ̀ àwọn ọmọ, ní fífi ìyìn OLúWA, àti ipa rẹ̀ àti iṣẹ́ ìyanu tó ti ṣe hàn fún ìran tí ń bọ̀.
Ṣàwárí Saamu 78:4
3
Saamu 78:6
Nítorí náà, àwọn ìran tí ń bọ̀ yóò mọ̀ wọ́n bẹ́ẹ̀ ni àwọn ọmọ tí a kò tí ì bí tí yóò dìde tí wọn yóò sọ fún àwọn ọmọ wọn
Ṣàwárí Saamu 78:6
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò