1
Saamu 77:11-12
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Èmi ó rántí iṣẹ́ OLúWA: bẹ́ẹ̀ ni, èmi ó rántí iṣẹ́ ìyanu rẹ̀ ọjọ́ pípẹ́. Èmi ṣàṣàrò lórí iṣẹ́ rẹ gbogbo pẹ̀lú, ènìyàn sì máa sọ̀rọ̀ gbogbo iṣẹ́ agbára rẹ.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 77:11-12
2
Saamu 77:14
Ìwọ ni Ọlọ́run tó ń ṣe ìyanu; ìwọ fi agbára rẹ hàn nínú àwọn ènìyàn.
Ṣàwárí Saamu 77:14
3
Saamu 77:13
Ọlọ́run, Ọ̀nà rẹ jẹ́ mímọ́. Ọlọ́run wo ni ó sì tóbi bí Ọlọ́run wa?
Ṣàwárí Saamu 77:13
4
Saamu 77:1-2
Mó kígbe sí Ọlọ́run fún ìrànlọ́wọ́; mo kígbe sí Ọlọ́run láti gbọ́ tèmi. Nígbà tí mo wà nínú ìpọ́njú, mo wá OLúWA; ní òru ni mo na ọwọ́ mi jáde ní àìkáárẹ̀ ọkàn mí sì kọ̀ láti tù ú nínú.
Ṣàwárí Saamu 77:1-2
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò