1
Saamu 106:1
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Yin OLúWA! Ẹ fi ìyìn fún OLúWA, nítorí tí ó ṣeun. Ẹ fi ọpẹ́ fún OLúWA nítorí tí ó ṣeun; Nítorí tí ìfẹ́ rẹ̀ dúró láéláé.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 106:1
2
Saamu 106:3
Ìbùkún ni fún àwọn tí ń pa ìdájọ́ mọ́? Ẹni tí n ṣe ohun tí ó tọ́.
Ṣàwárí Saamu 106:3
3
Saamu 106:4-5
Rántí mi, OLúWA, Nígbà tí o bá fi ojúrere rẹ hàn, wá sí ìhà mi nígbà tí ìwọ bá gbà wọ́n, Kí èmi kí ó lè jẹ ìgbádùn àlàáfíà àwọn tí ìwọ ti yàn, kí èmi kí ó sì darapọ̀ mọ́ àwọn ènìyàn, ìní rẹ láti jọ yìn ọ́ lógo.
Ṣàwárí Saamu 106:4-5
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò