1
Saamu 105:1
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ẹ fi ọpẹ́ fún OLúWA, ké pe orúkọ rẹ̀: Jẹ́ kí a mọ ohun tí ó ṣe láàrín àwọn orílẹ̀-èdè
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 105:1
2
Saamu 105:4
Wá OLúWA àti ipá rẹ̀; wa ojú rẹ̀ nígbà gbogbo.
Ṣàwárí Saamu 105:4
3
Saamu 105:3
Ṣògo nínú orúkọ mímọ́ rẹ̀: Jẹ́ kí ọkàn àwọn tí ń wá OLúWA kí ó yọ̀.
Ṣàwárí Saamu 105:3
4
Saamu 105:2
Kọrin sí i, kọrin ìyìn sí i; sọ ti iṣẹ́ ìyanu rẹ̀ gbogbo.
Ṣàwárí Saamu 105:2
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò