1
Lefitiku 18:22
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
“ ‘Ìwọ kò gbọdọ̀ bá ọkùnrin lòpọ̀ bí ìgbà tí ènìyàn ń bá obìnrin lòpọ̀: ìríra ni èyí jẹ́.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Lefitiku 18:22
2
Lefitiku 18:23
“ ‘Ìwọ kò gbọdọ̀ bá ẹranko lòpọ̀ kí ìwọ má ba à ba ara rẹ jẹ́. Obìnrin kò sì gbọdọ̀ jọ̀wọ́ ara rẹ̀ sílẹ̀ fún ẹranko láti bá a lòpọ̀, ohun tó lòdì ni.
Ṣàwárí Lefitiku 18:23
3
Lefitiku 18:21
“ ‘Ìwọ kò gbọdọ̀ fi èyíkéyìí nínú àwọn ọmọ rẹ rú ẹbọ lórí pẹpẹ sí òrìṣà Moleki, kí o sì tipa bẹ́ẹ̀ ba orúkọ Ọlọ́run rẹ jẹ́. Èmi ni OLúWA.
Ṣàwárí Lefitiku 18:21
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò