1
Esekiẹli 13:3
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Báyìí ni OLúWA Olódùmarè wí: Ègbé ni fún àwọn aṣiwèrè wòlíì tó ń tẹ̀lé ẹ̀mí ara wọn tí wọn kò sì rí nǹkan kan!
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Esekiẹli 13:3
2
Esekiẹli 13:6
Ìran àti àfọ̀ṣẹ wọn jẹ́ èké. Wọ́n wí pé, “OLúWA wí” nígbà tí OLúWA kò rán wọn, síbẹ̀ wọ́n fẹ́ kí OLúWA mú ọ̀rọ̀ wọn ṣẹ.
Ṣàwárí Esekiẹli 13:6
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò