1
Esekiẹli 12:28
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
“Nítorí náà sọ fún wọn, ‘Báyìí ni OLúWA Olódùmarè wí: Kò sí ọ̀kan nínú ọ̀rọ̀ mi tí yóò sún síwájú mọ́; ṣùgbọ́n ọ̀rọ̀ tí mo bá sọ yóò ṣẹ.’ ”
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Esekiẹli 12:28
2
Esekiẹli 12:25
Ṣùgbọ́n Èmi OLúWA yóò sọ̀rọ̀, ọ̀rọ̀ tí mo sọ yóò sì ṣẹ láì falẹ̀. Báyìí ni OLúWA Olódùmarè wí, ní àsìkò yín, ẹ̀yin ọlọ̀tẹ̀ ilé ni Èmi yóò mú ọ̀rọ̀ yówù tí mo bá sọ ṣẹ.’ ”
Ṣàwárí Esekiẹli 12:25
3
Esekiẹli 12:2
“Ọmọ ènìyàn, ìwọ ń gbé ní àárín ọlọ̀tẹ̀ ènìyàn. Wọ́n lójú láti fi ríran, ṣùgbọ́n wọn kò ríran, bẹ́ẹ̀ ni wọ́n létí láti fi gbọ́rọ̀ ṣùgbọ́n wọn kò gbọ́rọ̀, torí pé ọlọ̀tẹ̀ ènìyàn ni wọ́n.
Ṣàwárí Esekiẹli 12:2
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò