1
Eksodu 40:38
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Nítorí náà àwọsánmọ̀ OLúWA wà lórí àgọ́ ní ọ̀sán, iná sì wà nínú àwọsánmọ̀ ní alẹ́, ní ojú gbogbo ilé Israẹli ní gbogbo ìrìnàjò wọn.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Eksodu 40:38
2
Eksodu 40:34-35
Nígbà náà ni àwọsánmọ̀ bo àgọ́ àjọ, ògo OLúWA bo àgọ́ náà. Mose kò sì lè wọ inú àgọ́ àjọ, nítorí àwọsánmọ̀ wà ní orí àgọ́, ògo OLúWA sì ti kún inú àgọ́ náà.
Ṣàwárí Eksodu 40:34-35
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò