1
Eksodu 39:43
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Mose bẹ iṣẹ́ náà wò, ó sì rí i wí pé wọ́n ti ṣe é gẹ́gẹ́ bí OLúWA ti pàṣẹ. Nítorí náà Mose sì bùkún fún wọn.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Eksodu 39:43
2
Eksodu 39:42
Àwọn ọmọ Israẹli ti ṣe gbogbo iṣẹ́ náà gẹ́gẹ́ bí OLúWA ti pàṣẹ fún Mose.
Ṣàwárí Eksodu 39:42
3
Eksodu 39:32
Bẹ́ẹ̀ ni gbogbo iṣẹ́ àgọ́ náà, ti àgọ́ àjọ parí. Àwọn ọmọ Israẹli ṣe ohun gbogbo gẹ́gẹ́ bí OLúWA ti pàṣẹ fún Mose.
Ṣàwárí Eksodu 39:32
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò