1
1 Samuẹli 2:2
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
“Kò sí ẹni tí ó mọ́ bi OLúWA; kò sí ẹlòmíràn bí kò ṣe ìwọ; kò sì sí àpáta bi Ọlọ́run wa.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí 1 Samuẹli 2:2
2
1 Samuẹli 2:8
Ó gbé tálákà sókè láti inú erùpẹ̀ wá, ó gbé alágbe sókè láti orí òkìtì eérú wá, láti mú wọn jókòó pẹ̀lú àwọn ọmọ-aládé, láti mu wọn jogún ìtẹ́ ògo: “Nítorí pé ọ̀wọ́n ayé ti OLúWA ni, ó sì ti gbé ayé ka orí wọn
Ṣàwárí 1 Samuẹli 2:8
3
1 Samuẹli 2:9
Yóò pa ẹsẹ̀ àwọn ènìyàn mímọ́ rẹ̀ mọ́, àwọn ènìyàn búburú ni yóò dákẹ́ ní òkùnkùn. “Nípa agbára kò sí ọkùnrin tí yóò borí.
Ṣàwárí 1 Samuẹli 2:9
4
1 Samuẹli 2:7
OLúWA sọ di tálákà; ó sì sọ di ọlọ́rọ̀; ó rẹ̀ sílẹ̀, ó sì gbé sókè.
Ṣàwárí 1 Samuẹli 2:7
5
1 Samuẹli 2:6
“OLúWA pa ó sì sọ di ààyè; ó mú sọ̀kalẹ̀ lọ sí isà òkú, ó sì gbé dìde.
Ṣàwárí 1 Samuẹli 2:6
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò