I. Sam 2:8
I. Sam 2:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Ó gbé tálákà sókè láti inú erùpẹ̀ wá, ó gbé alágbe sókè láti orí òkìtì eérú wá, láti mú wọn jókòó pẹ̀lú àwọn ọmọ-aládé, láti mu wọn jogún ìtẹ́ ògo: “Nítorí pé ọ̀wọ́n ayé ti OLúWA ni, ó sì ti gbé ayé ka orí wọn
Pín
Kà I. Sam 2