1
Ifi 16:15
Bibeli Mimọ
Kiyesi i, mo mbọ̀ bi olè. Ibukún ni fun ẹniti nṣọna, ti o si npa aṣọ rẹ̀ mọ́, ki o má bã rìn ni ìhoho, nwọn a si ri itiju rẹ̀.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Ifi 16:15
2
Ifi 16:12
Ẹkẹfa si tú ìgo tirẹ̀ sori odò nla Eufrate; omi rẹ̀ si gbẹ, ki a le pese ọna fun awọn ọba ati ìla-õrùn wá.
Ṣàwárí Ifi 16:12
3
Ifi 16:14
Nitori ẹmi èṣu ni wọn, ti nṣe iṣẹ-iyanu, awọn ti njade lọ sọdọ awọn ọba gbogbo ilẹ aiye, lati gbá wọn jọ si ogun ọjọ nla Ọlọrun Olodumare.
Ṣàwárí Ifi 16:14
4
Ifi 16:13
Mo si ri awọn ẹmí aimọ́ mẹta bi ọ̀pọlọ́, nwọn ti ẹnu dragoni na ati ẹnu ẹranko na ati ẹnu woli eke na jade wá.
Ṣàwárí Ifi 16:13
5
Ifi 16:9
A si fi õru nla jo awọn enia lara, nwọn si sọ̀rọ-òdi si orukọ Ọlọrun, ẹniti o li agbara lori iyọnu wọnyi: nwọn kò si ronupiwada lati fi ogo fun u.
Ṣàwárí Ifi 16:9
6
Ifi 16:2
Ekini si lọ, o si tú ìgo tirẹ̀ si ori ilẹ aiye; egbò kikẹ̀ ti o si dibajẹ si dá awọn enia ti o ni àmi ẹranko na, ati awọn ti nforibalẹ fun aworan rẹ̀.
Ṣàwárí Ifi 16:2
7
Ifi 16:16
O si gbá wọn jọ si ibikan ti a npè ni Har-mageddoni li ède Heberu.
Ṣàwárí Ifi 16:16
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò