1
O. Daf 67:1
Bibeli Mimọ
KI Ọlọrun ki o ṣãnu fun wa, ki o si busi i fun wa; ki o si ṣe oju rẹ̀ ki o mọlẹ si wa lara
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 67:1
2
O. Daf 67:7
Ọlọrun yio busi i fun wa; ati gbogbo opin aiye yio si ma bẹ̀ru rẹ̀.
Ṣàwárí O. Daf 67:7
3
O. Daf 67:4
Jẹ ki inu awọn orilẹ-ède ki o dùn, ki nwọn ki o ma kọrin fun ayọ̀: nitoriti iwọ o fi ododo ṣe idajọ enia, iwọ o si jọba awọn orilẹ-ède li aiye.
Ṣàwárí O. Daf 67:4
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò