1
O. Daf 50:14-15
Bibeli Mimọ
Ru ẹbọ-ọpẹ si Ọlọrun, ki o si san ẹjẹ́ rẹ fun Ọga-ogo. Ki o si kepè mi ni ọjọ ipọnju: emi o gbà ọ, iwọ o si ma yìn mi logo.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 50:14-15
2
O. Daf 50:10-11
Nitori gbogbo ẹran igbo ni ti emi, ati ẹrankẹran lori ẹgbẹrun òke. Emi mọ̀ gbogbo ẹiyẹ awọn oke nla: ati ẹranko igbẹ ni ti emi.
Ṣàwárí O. Daf 50:10-11
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò