1
O. Daf 49:20
Bibeli Mimọ
Ọkunrin ti o wà ninu ọlá, ti kò moye, o dabi ẹranko ti o ṣegbe.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 49:20
2
O. Daf 49:15
Ṣugbọn Ọlọrun ni yio rà ọkàn mi lọwọ isa-okú: nitoripe on o gbà mi.
Ṣàwárí O. Daf 49:15
3
O. Daf 49:16-17
Iwọ máṣe bẹ̀ru, nitori ẹnikan di ọlọrọ̀, nitori iyìn ile rẹ̀ npọ̀ si i. Nitoripe, igbati o ba kú, kì yio kó ohun kan lọ: ogo rẹ̀ kì yio sọkalẹ tọ̀ ọ lẹhin lọ.
Ṣàwárí O. Daf 49:16-17
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò