1
O. Daf 107:1
Bibeli Mimọ
Ẹ fi ọpẹ fun Oluwa, nitori ti o ṣeun: nitori ti ãnu rẹ̀ duro lailai.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 107:1
2
O. Daf 107:20
O rán ọ̀rọ rẹ̀, o si mu wọn lara da, o si gbà wọn kuro ninu iparun wọn.
Ṣàwárí O. Daf 107:20
3
O. Daf 107:8-9
Enia iba ma yìn Oluwa nitori ore rẹ̀, ati nitori iṣẹ iyanu rẹ̀ si awọn ọmọ enia! Nitori ti o tẹ́ ifẹ ọkàn lọrun, o si fi ire kún ọkàn ti ebi npa.
Ṣàwárí O. Daf 107:8-9
4
O. Daf 107:28-29
Nigbana ni nwọn kigbe pè Oluwa ninu ipọnju wọn, o si yọ wọn kuro ninu iṣẹ́ wọn. O sọ ìji di idakẹ-rọrọ́, bẹ̃ni riru omi rẹ̀ duro jẹ.
Ṣàwárí O. Daf 107:28-29
5
O. Daf 107:6
Nigbana ni nwọn kigbe pè Oluwa ninu ipọnju wọn, o si yọ wọn kuro ninu iṣẹ́ wọn
Ṣàwárí O. Daf 107:6
6
O. Daf 107:19
Nigbana ni nwọn kigbe pè Oluwa ninu ipọnju wọn, o si gbà wọn ninu iṣẹ́ wọn.
Ṣàwárí O. Daf 107:19
7
O. Daf 107:13
Ṣàwárí O. Daf 107:13
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò