1
O. Daf 106:1
Bibeli Mimọ
Ẹ fi iyìn fun Oluwa! Ẹ fi ọpẹ fun Oluwa: nitoriti o ṣeun: nitoriti ti ãnu rẹ̀ duro lailai.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 106:1
2
O. Daf 106:3
Ibukún ni fun awọn ti npa idajọ mọ́, ati ẹniti nṣe ododo ni igbagbogbo.
Ṣàwárí O. Daf 106:3
3
O. Daf 106:4-5
Oluwa, fi oju-rere ti iwọ ni si awọn enia rẹ ṣe iranti mi: fi igbala rẹ bẹ̀ mi wò. Ki emi ki o le ri ire awọn ayanfẹ rẹ, ki emi ki o le yọ̀ ninu ayọ̀ orilẹ-ède rẹ, ki emi ki o le ma ṣogo pẹlu awọn enia ilẹ-ini rẹ.
Ṣàwárí O. Daf 106:4-5
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò