1
O. Daf 103:2
Bibeli Mimọ
Fi ibukún fun Oluwa, iwọ ọkàn mi, má si ṣe gbagbe gbogbo ore rẹ̀
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 103:2
2
O. Daf 103:3-5
Ẹniti o dari gbogbo ẹ̀ṣẹ rẹ jì; ẹniti o si tan gbogbo àrun rẹ, Ẹniti o ra ẹmi rẹ kuro ninu iparun; ẹniti o fi iṣeun-ifẹ ati iyọ́nu de ọ li ade: Ẹniti o fi ohun didara tẹ́ ọ lọrun: bẹ̃ni igba ewe rẹ di ọtun bi ti idì.
Ṣàwárí O. Daf 103:3-5
3
O. Daf 103:1
FI ibukún fun Oluwa, iwọ ọkàn mi, ati gbogbo ohun ti o wà ninu mi, fi ibukún fun orukọ rẹ̀ mimọ́.
Ṣàwárí O. Daf 103:1
4
O. Daf 103:13
Bi baba ti iṣe iyọ́nu si awọn ọmọ, bẹ̃li Oluwa nṣe iyọ́nu si awọn ti o bẹ̀ru rẹ̀.
Ṣàwárí O. Daf 103:13
5
O. Daf 103:12
Bi ila-õrun ti jina si ìwọ-õrun, bẹ̃li o mu irekọja wa jina kuro lọdọ wa.
Ṣàwárí O. Daf 103:12
6
O. Daf 103:8
Oluwa li alãnu ati olõre, o lọra ati binu, o si pọ̀ li ãnu.
Ṣàwárí O. Daf 103:8
7
O. Daf 103:10-11
On kì iṣe si wa gẹgẹ bi ẹ̀ṣẹ wa; bẹ̃ni kì isan a fun wa gẹgẹ bi aiṣedede wa. Nitori pe, bi ọrun ti ga si ilẹ, bẹ̃li ãnu rẹ̀ tobi si awọn ti o bẹ̀ru rẹ̀.
Ṣàwárí O. Daf 103:10-11
8
O. Daf 103:19
Oluwa ti pèse itẹ́ rẹ̀ ninu ọrun; ijọba rẹ̀ li o si bori ohun gbogbo
Ṣàwárí O. Daf 103:19
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò