1
O. Daf 102:2
Bibeli Mimọ
Máṣe pa oju rẹ mọ́ kuro lara mi li ọjọ ti emi wà ninu ipọnju; dẹ eti rẹ si mi: li ọjọ ti mo ba pè, da mi lohùn-lọgan.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 102:2
2
O. Daf 102:1
GBỌ adura mi, Oluwa, ki o si jẹ ki igbe mi ki o wá sọdọ rẹ.
Ṣàwárí O. Daf 102:1
3
O. Daf 102:12
Ṣugbọn iwọ, Oluwa, ni yio duro lailai; ati iranti rẹ lati iran dé iran.
Ṣàwárí O. Daf 102:12
4
O. Daf 102:17
Yio juba adura awọn alaini, kì yio si gàn adura wọn.
Ṣàwárí O. Daf 102:17
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò