1
Jak 4:7
Bibeli Mimọ
Nitorina ẹ tẹriba fun Ọlọrun. Ẹ kọ oju ija si Èṣu, on ó si sá kuro lọdọ nyin.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Jak 4:7
2
Jak 4:8
Ẹ sunmọ Ọlọrun, on o si sunmọ nyin, Ẹ wẹ̀ ọwọ́ nyin mọ́, ẹnyin ẹlẹṣẹ; ẹ si ṣe ọkàn nyin ni mimọ́, ẹnyin oniye meji.
Ṣàwárí Jak 4:8
3
Jak 4:10
Ẹ rẹ̀ ara nyin silẹ niwaju Oluwa, on o si gbé nyin ga.
Ṣàwárí Jak 4:10
4
Jak 4:6
Ṣugbọn o nfunni li ore-ọfẹ si i. Nitorina li o ṣe wipe, Ọlọrun kọ oju ija si awọn agberaga, ṣugbọn o fi ore-ọfẹ fun awọn onirẹlẹ ọkàn.
Ṣàwárí Jak 4:6
5
Jak 4:17
Nitorina ẹniti o ba mọ̀ rere iṣe ti kò si ṣe, ẹ̀ṣẹ ni fun u.
Ṣàwárí Jak 4:17
6
Jak 4:3
Ẹnyin bère, ẹ kò si ri gbà, nitoriti ẹnyin ṣì i bère, ki ẹnyin ki o le lò o fun ifẹkufẹ ara nyin.
Ṣàwárí Jak 4:3
7
Jak 4:4
Ẹnyin panṣaga ọkunrin, ati panṣaga obinrin, ẹ kò mọ̀ pe ìbarẹ́ aiye ìṣọtá Ọlọrun ni? nitorina ẹnikẹni ti o ba fẹ lati jẹ́ ọrẹ aiye di ọtá Ọlọrun.
Ṣàwárí Jak 4:4
8
Jak 4:14
Nigbati ẹnyin kò mọ̀ ohun ti yio hù lọla. Kili ẹmí nyin? Ikũku sá ni nyin, ti o hàn nigba diẹ, lẹhinna a si túka lọ.
Ṣàwárí Jak 4:14
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò