1
Jak 2:17
Bibeli Mimọ
Bẹ̃ si ni igbagbọ́, bi kò ba ni iṣẹ, o kú ninu ara.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Jak 2:17
2
Jak 2:26
Nitori bi ara li aisi ẹmí ti jẹ́ okú, bẹ̃ gẹgẹ pẹlu ni igbagbọ́ li aisi iṣẹ jẹ́ okú.
Ṣàwárí Jak 2:26
3
Jak 2:14
Ere kili o jẹ, ará mi, bi ẹnikan wipe on ni igbagbọ́, ṣugbọn ti kò ni iṣẹ? igbagbọ́ nì le gbà a là bi?
Ṣàwárí Jak 2:14
4
Jak 2:19
Iwọ gbagbọ́ pe Ọlọrun kan ni mbẹ; o dara: awọn ẹmí èṣu pẹlu gbagbọ́, nwọn si warìri.
Ṣàwárí Jak 2:19
5
Jak 2:18
Ṣugbọn ẹnikan le wipe, Iwọ ni igbagbọ́, emi si ni iṣẹ: fi igbagbọ́ rẹ hàn mi li aisi iṣẹ, emi o si fi igbagbọ́ mi hàn ọ nipa iṣẹ mi.
Ṣàwárí Jak 2:18
6
Jak 2:13
Nitori ẹniti kò ṣãnu, li a o ṣe idajọ fun laisi ãnu; ãnu nṣogo lori idajọ.
Ṣàwárí Jak 2:13
7
Jak 2:24
Njẹ ẹnyin ri pe nipa iṣẹ li a ndá enia lare, kì iṣe nipa igbagbọ́ nikan.
Ṣàwárí Jak 2:24
8
Jak 2:22
Iwọ ri pe igbagbọ́ bá iṣẹ rẹ̀ rìn, ati pe nipa iṣẹ li a sọ igbagbọ́ di pipé.
Ṣàwárí Jak 2:22
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò