1
Iṣe Apo 12:5
Bibeli Mimọ
Nitorina nwọn pa Peteru mọ́ ninu tubu: ṣugbọn ijọ nfi itara gbadura sọdọ Ọlọrun fun u.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Iṣe Apo 12:5
2
Iṣe Apo 12:7
Si wo o, angẹli Oluwa duro tì i, imọlẹ si mọ́ ninu tubu: nigbati o si lù Peteru pẹ́pẹ li ẹgbẹ o ji i, o ni, Dide kánkan. Ẹwọn rẹ̀ si bọ́ silẹ kuro lọwọ rẹ̀.
Ṣàwárí Iṣe Apo 12:7
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò