1
II. Kor 13:5
Bibeli Mimọ
Ẹ mã wadi ara nyin, bi ẹnyin bá wà ninu igbagbọ́; ẹ mã dan ara nyin wò. Tabi ẹnyin tikaranyin kò mọ̀ ara nyin pe Jesu Kristi wà ninu nyin? afi bi ẹnyin ba jẹ awọn ti a tanù.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí II. Kor 13:5
2
II. Kor 13:14
Ore-ọfẹ Jesu Kristi Oluwa, ati ifẹ Ọlọrun, ati ìdapọ ti Ẹmí Mimọ́, ki o wà pẹlu gbogbo nyin. Amin.
Ṣàwárí II. Kor 13:14
3
II. Kor 13:11
Li akotan, ará, odigboṣe. Ẹ jẹ pipé, ẹ tújuka, ẹ jẹ oninu kan, ẹ mã wà li alafia; Ọlọrun ifẹ ati ti alafia yio wà pẹlu nyin.
Ṣàwárí II. Kor 13:11
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò