1
ORIN DAFIDI 98:1
Yoruba Bible
Ẹ kọ orin titun sí OLUWA, nítorí tí ó ti ṣe ohun ìyanu; agbára ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀, ati apá mímọ́ rẹ̀ ni ó fi ṣẹgun.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 98:1
2
ORIN DAFIDI 98:4
Gbogbo ayé, ẹ hó ìhó ayọ̀ sí OLUWA; ẹ bú sí orin ayọ̀, kí ẹ sì kọ orin ìyìn.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 98:4
3
ORIN DAFIDI 98:9
níwájú OLUWA, nítorí pé ó ń bọ̀ wá ṣe ìdájọ́ ayé. Yóo fi òdodo ṣe ìdájọ́ ayé; yóo sì fi ẹ̀tọ́ ṣe ìdájọ́ àwọn eniyan.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 98:9
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò