1
ORIN DAFIDI 66:18
Yoruba Bible
Bí mo bá gba ẹ̀ṣẹ̀ láyè ní ọkàn mi, OLUWA ìbá tí gbọ́ tèmi.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 66:18
2
ORIN DAFIDI 66:20
Ìyìn ni fún Ọlọrun, nítorí pé kò kọ adura mi; kò sì mú kí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ kúrò lórí mi.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 66:20
3
ORIN DAFIDI 66:3
Ẹ sọ fún Ọlọrun pé, “Iṣẹ́ rẹ bani lẹ́rù pupọ, agbára rẹ pọ̀ tóbẹ́ẹ̀ gẹ́ẹ́, tí àwọn ọ̀tá rẹ fi ń fi ìbẹ̀rù tẹríba fún ọ.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 66:3
4
ORIN DAFIDI 66:1-2
Gbogbo ayé, ẹ hó ìhó ayọ̀ sí Ọlọrun. Ẹ kọ orin ògo yin orúkọ rẹ̀; ẹ yìn ín, ẹ fògo fún un!
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 66:1-2
5
ORIN DAFIDI 66:10
Nítorí ìwọ, Ọlọrun, ti dán wa wò; o ti dán wa wò bíi fadaka tí a dà ninu iná.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 66:10
6
ORIN DAFIDI 66:16
Ẹ wá gbọ́, gbogbo ẹ̀yin tí ó bẹ̀rù Ọlọrun, n óo sì ròyìn ohun tí ó ṣe fún mi.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 66:16
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò