1
ORIN DAFIDI 6:9
Yoruba Bible
OLUWA ti gbọ́ ẹ̀bẹ̀ mi, OLUWA ti tẹ́wọ́gba adura mi.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 6:9
2
ORIN DAFIDI 6:2
Ṣàánú mi, OLUWA, nítorí àárẹ̀ mú ọkàn mi, OLUWA, wò mí sàn nítorí ara ń ni mí dé egungun.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 6:2
3
ORIN DAFIDI 6:8
Ẹ kúrò lọ́dọ̀ mi, gbogbo ẹ̀yin oníṣẹ́ ibi, nítorí OLUWA ti gbọ́ ìró ẹkún mi.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 6:8
4
ORIN DAFIDI 6:4
OLUWA, pada wá gbà mí, gbà mí là nítorí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 6:4
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò