Oluwa, ṣãnu fun mi; nitori ailera mi: Oluwa, mu mi lara da; nitori ti ara kan egungun mi.
Ṣàánú mi, OLUWA, nítorí àárẹ̀ mú ọkàn mi, OLUWA, wò mí sàn nítorí ara ń ni mí dé egungun.
Ṣàánú fún mi, OLúWA, nítorí èmi ń kú lọ; OLúWA, wò mí sán, nítorí egungun mi wà nínú ìnira.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò