1
ORIN DAFIDI 150:6
Yoruba Bible
Kí gbogbo nǹkan ẹlẹ́mìí yin OLUWA! Ẹ yin OLUWA!
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 150:6
2
ORIN DAFIDI 150:1
Ẹ yin OLUWA! Ẹ yin Ọlọrun ninu ibi mímọ́ rẹ̀; ẹ yìn ín ninu òfuurufú rẹ̀ tí ó lágbára.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 150:1
3
ORIN DAFIDI 150:2
Ẹ yìn ín fún iṣẹ́ ńlá rẹ̀; ẹ yìn ín nítorí pé ó tóbi pupọ.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 150:2
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò