1
ORIN DAFIDI 134:2
Yoruba Bible
Ẹ gbé ọwọ́ yín sókè, kí ẹ gbadura ninu ilé mímọ́ rẹ̀, kí ẹ sì yin OLUWA.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 134:2
2
ORIN DAFIDI 134:1
Ẹ wá, ẹ yin OLUWA, gbogbo ẹ̀yin iranṣẹ rẹ̀, gbogbo ẹ̀yin tí ń sìn ín ninu ilé rẹ̀ lóru.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 134:1
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò