Ẹ kiyesi i, ẹ fi ibukún fun Oluwa, gbogbo ẹnyin iranṣẹ Oluwa, ti nduro ni ile Oluwa li oru.
Ẹ wá, ẹ yin OLUWA, gbogbo ẹ̀yin iranṣẹ rẹ̀, gbogbo ẹ̀yin tí ń sìn ín ninu ilé rẹ̀ lóru.
Ẹ kíyèsi i, ẹ fi ìbùkún fún OLúWA, gbogbo ẹ̀yin ìránṣẹ́ OLúWA, tí ó dúró ní ilé OLúWA ní òru.
YouVersion nlo awọn kuki lati ṣe adani iriri rẹ. Nipa lilo oju opo wẹẹbu wa, o gba lilo awọn kuki wa gẹgẹbi a ti ṣalaye ninu Eto Afihan wa
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò