1
NỌMBA 23:19
Yoruba Bible
Ọlọrun kò jọ eniyan tí máa ń purọ́, bẹ́ẹ̀ ni kì í ṣe eniyan tí máa ń yí ọkàn pada. Ohun tí ó bá ti sọ ni yóo ṣe, bí ó bá sì sọ̀rọ̀ yóo rí bẹ́ẹ̀.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí NỌMBA 23:19
2
NỌMBA 23:23
Kò sí òògùn kan tí ó lè ran Jakọbu, bẹ́ẹ̀ ni àfọ̀ṣẹ kan kò lè ran Israẹli. Wò ó! Àwọn eniyan yóo máa wí nípa Israẹli pé, ‘Wo ohun tí Ọlọrun ṣe!’
Ṣàwárí NỌMBA 23:23
3
NỌMBA 23:20
OLUWA ti sọ fún mi pé kí n bukun wọn, Ọlọrun pàápàá ti bukun wọn, èmi kò lè mú ibukun náà kúrò.
Ṣàwárí NỌMBA 23:20
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò