Ninu àlá, lójú ìran ní ààrin òru,
nígbà tí eniyan bá sun oorun àsùnwọra, lórí ibùsùn wọn,
Ọlọrun a máa ṣí wọn létí,
a máa kìlọ̀ fún wọn, a sì máa dẹ́rùbà wọ́n,
kí ó lè dá wọn lẹ́kun ìṣe wọn,
kí ó lè gba ìgbéraga lọ́wọ́ wọn;
kí ó lè yọ ọkàn eniyan kúrò ninu ọ̀fìn ìparun,
kí ó má baà kú ikú idà.