1
AISAYA 66:2
Yoruba Bible
Ọwọ́ mi ni mo fi ṣe gbogbo nǹkan wọnyi, tèmi sì ni gbogbo wọn. Ẹni tí n óo kà kún, ni onírẹ̀lẹ̀ ati oníròbìnújẹ́ eniyan, tí ó ń wárìrì nítorí ọ̀rọ̀ mi.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí AISAYA 66:2
2
AISAYA 66:1
OLUWA ní: “Ọ̀run ni ìtẹ́ mi, ayé ni àpótí ìtìsẹ̀ mi. Ilé tí ẹ kọ́ fún mi dà? Níbo sì ni ibi ìsinmi mi wà?
Ṣàwárí AISAYA 66:1
3
AISAYA 66:13
N óo rẹ̀ yín lẹ́kún bí ọmọ tí ìyá rẹ̀ rẹ̀ lẹ́kún, bẹ́ẹ̀ ni n óo ṣe tù yín ninu ní Jerusalẹmu.
Ṣàwárí AISAYA 66:13
4
AISAYA 66:22
“Bí ọ̀run tuntun ati ayé tuntun tí n óo dá, yóo ṣe máa wà níwájú mi, bẹ́ẹ̀ ni arọmọdọmọ ati orúkọ rẹ̀ yóo máa wà.
Ṣàwárí AISAYA 66:22
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò