1
ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 27:25
Yoruba Bible
Nítorí náà ẹ̀yin eniyan, ẹ ṣara gírí, nítorí mo gba Ọlọrun gbọ́ pé bí ó ti sọ fún mi ni yóo rí.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 27:25
2
ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 27:23-24
Nítorí ní alẹ́ àná, angẹli Ọlọrun mi, tí mò ń sìn dúró tì mí, ó ní, ‘Má bẹ̀rù, Paulu. Dandan ni kí o dé iwájú Kesari. Mo fẹ́ kí o mọ̀ pé Ọlọrun ti fi ẹ̀mí gbogbo àwọn ẹni tí ó wọkọ̀ pẹlu rẹ jíǹkí rẹ.’
Ṣàwárí ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 27:23-24
3
ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 27:22
Ṣugbọn bí ó ti rí yìí náà, mo gbà yín níyànjú pé kí ẹ ṣara gírí. Ẹ̀mí ẹnikẹ́ni ninu yín kò ní ṣòfò; ọkọ̀ nìkan ni yóo ṣòfò.
Ṣàwárí ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 27:22
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò