ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 27:22
ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 27:22 YCE
Ṣugbọn bí ó ti rí yìí náà, mo gbà yín níyànjú pé kí ẹ ṣara gírí. Ẹ̀mí ẹnikẹ́ni ninu yín kò ní ṣòfò; ọkọ̀ nìkan ni yóo ṣòfò.