1
ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 20:35
Yoruba Bible
Mo ti fihàn yín pé bẹ́ẹ̀ ni a níláti ṣiṣẹ́ láti ran àwọn aláìlera lọ́wọ́. Kí á máa ranti àwọn ọ̀rọ̀ Oluwa Jesu, nítorí òun fúnra rẹ̀ sọ pé, ‘Ayọ̀ pọ̀ ninu kí a máa fúnni ní nǹkan ju kí á máa gbà lọ.’ ”
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 20:35
2
ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 20:24
Ṣugbọn n kò ka ẹ̀mí mi sí ohunkohun tí ó ní iye lórí fún ara mi. Ohun tí mò ń lépa ni láti parí iré ìje mi ati iṣẹ́ tí mo gbà lọ́wọ́ Oluwa mi Jesu, èyí ni pé kí n tẹnu mọ́ ìyìn rere oore-ọ̀fẹ́ Ọlọrun.
Ṣàwárí ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 20:24
3
ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 20:28
Ẹ ṣọ́ra yín, ẹ sì ṣọ́ agbo tí Ẹ̀mí Mímọ́ fi yín ṣe alabojuto lórí rẹ̀, kí ẹ máa bọ́ ìjọ Ọlọrun tí ó fi ẹ̀jẹ̀ Ọmọ rẹ̀ ṣe ní tirẹ̀.
Ṣàwárí ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 20:28
4
ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 20:32
“Nisinsinyii, mo fi yín lé Ọlọrun lọ́wọ́ ati ọ̀rọ̀ oore-ọ̀fẹ́ rẹ̀ tí ó lè mu yín dàgbà, tí ó sì lè fun yín ní ogún pẹlu gbogbo àwọn tí a ti sọ di mímọ́.
Ṣàwárí ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 20:32
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò