1
SAMUẸLI KEJI 24:24
Yoruba Bible
Ṣugbọn ọba dá a lóhùn pé, “Rárá o, n óo san owó rẹ̀ fún ọ, nítorí pé ohunkohun tí kò bá ní ná mi lówó, n kò ní fi rúbọ sí OLUWA Ọlọrun mi.” Dafidi bá ra ibi ìpakà ati àwọn akọ mààlúù náà, ní aadọta ṣekeli owó fadaka.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí SAMUẸLI KEJI 24:24
2
SAMUẸLI KEJI 24:25
Ó kọ́ pẹpẹ kan sibẹ fún OLUWA, ó sì rú ẹbọ sísun ati ẹbọ alaafia. OLUWA gbọ́ adura rẹ̀ lórí ilẹ̀ náà, àjàkálẹ̀ àrùn náà sì dáwọ́ dúró ní ilẹ̀ Israẹli.
Ṣàwárí SAMUẸLI KEJI 24:25
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò