1
KRONIKA KINNI 22:13
Yoruba Bible
Bí o bá pa gbogbo òfin tí Ọlọrun fún Israẹli láti ọwọ́ Mose mọ́, o óo ṣe rere. Múra, kí o sì ṣe ọkàn gírí, má bẹ̀rù, má sì ṣe jẹ́ kí àyà fò ọ́.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí KRONIKA KINNI 22:13
2
KRONIKA KINNI 22:19
Nítorí náà, ẹ fi tọkàntọkàn wá OLUWA Ọlọrun yín nisinsinyii. Ẹ múra kí ẹ kọ́ ilé ìsìn fún OLUWA Ọlọrun, kí ẹ baà lè gbé Àpótí Majẹmu OLUWA ati gbogbo ohun èlò mímọ́ fún ìsìn Ọlọrun lọ sinu ilé tí ẹ óo kọ́ fún OLUWA.”
Ṣàwárí KRONIKA KINNI 22:19
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò