← Àwon ètò
Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú O. Daf 119:105

Bí a ṣe ń ka bíbélì
3 Awọn ọjọ
Bíbélì jẹ́ ìwé pàtàkì nínú ìbáṣepọ̀ wa pẹ̀lú Ọlọ́run. Ó ju àkọsílẹ̀ lásán lọ, ṣùgbọ́n ó jẹ́ ìmísí láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run lórí bí ó ṣe yẹ kí àwọn onígbàgba máa lo ìgbésí-ayé wọn láyé. Ó tún jẹ́ àkọsílẹ̀ bí àwọn baba ìgbàgbọ́ kan ṣe bá Ọlọ́run rìn nígbà tí wọ́n wà láyé. Nítorí náà, ó ṣe pàtàkì láti ní òye bí a ṣe ń ka bíbélì.