Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú Mat 1
Ìhìnrere Matiu
28 Awọn ọjọ
Nínú ètò ẹsẹ̀-Bibeli-kan-lójúmọ́ yìí jàlẹ̀ Ìhìnrere ti Matiu, ìwọ yóò ṣalábapàdé Jesu Ọba: ìmúṣẹ àsọtẹ́lẹ̀ Májẹ̀mú Lailai, àti ìrètí gbogbo àgbáyé. Ṣàwárí bí o ṣe lè wọ Ìjọba Ọlọrun, mú Ìjọba Ọlọrun gbòòrò síi káàkiri àgbáyé, kí o sì ní ìrírí Ìjọba Ọlọrun, nípasẹ̀ àlàyé Matiu nípa àwọn ẹ̀kọ́, iṣẹ́ ìyanu, ikú, àti àjínde Jesu. YouVersion ni ó ṣàgbékalẹ̀ ètò yìí.
Awọn ihinrere
Ọgbọ̀n ọjọ́
Ètò yìí, tí a ṣe àkójọ àti àgbékalẹ̀ rẹẹ̀ nípasẹ̀ àwọn ẹgbẹ́ tí ó wà ní YouVersion.com, yoo ràń ọ́ lọ́wọ́ láti ka ìhìnrere mẹ́rẹ̀rin jálẹ̀ ní ọgbọ̀n ọjọ́. Gba òye nípa ìgbésí ayé ati iṣẹ́ Jésù ní ìgbà kéréje.
Jẹ́ kí a ka Bíbélì papọ̀ (April)
Ọgbọ̀n ọjọ́
Apa kerin ti onipin mejila, ètò yìí wà láti darí àwọn egbé tàbí ọrẹ nínú gbogbo Bíbélì lápapọ̀ ní ọjọ́ 365. Pe àwọn mìíràn láti darapọ̀ mọ́ ọ ní gbogbo ìgbà tí o bá bèrè apá titun ní osoosu. Ìpín yìí le bá Bíbélì Olohun ṣiṣẹ - tẹtisilẹ ní bíi ogun iṣẹju lójoojúmó! Apá kọọkan wá pẹ̀lú orí Bíbélì láti inú Májẹ̀mú àtijọ́ àti Majẹmu titun, pẹ̀lú Ìwé Orin Dáfídì láàrin wọn. Apá kerin ní àwọn Iwe Matiu, ati Jobu.