Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú Luk 23
Ìhìnrere Luku
24 Awọn ọjọ
Luku ṣe àkọsílẹ̀ ẹ̀kún àlàyé bí ẹlẹ́rìí nípa ìgbé-ayé, ikú àti àjínde Jesu. Ètò ẹsẹ̀-Bibeli-kan-lójúmọ́ yìí pèsè àkọsílẹ̀ lẹ́sẹẹsẹ tó dájú nípa àwọn ìṣẹ̀lẹ̀, ó sì tún mú wa mọ Olùgbàlà ológo náà. Òun wá láti wá àwọn tó sọnù láti gbà wọ́n là, Ó sì pè wá sínú iṣẹ́ àánú tí a rán-an wá fún náà. YouVersion ni ó ṣàgbékalẹ̀ ètò yìí.
Jẹ́ kí a ka Bíbélì papọ̀ (January)
Ọjọ́ Mòkanlé lọgbọ̀n
Apa kinni ti onipin mejila, ètò yìí wà láti darí àwọn egbé tàbí ọrẹ nínú gbogbo Bíbélì lápapọ̀ ní ọjọ́ 365. Pe àwọn mìíràn láti darapọ̀ mọ́ ọ ní gbogbo ìgbà tí o bá bèrè apá titun ní osoosu. Ìpín yìí le bá Bíbélì Olohun ṣiṣẹ - tẹtisilẹ ní bíi ogun iṣẹju lójoojúmó! Apá kọọkan wá pẹ̀lú orí Bíbélì láti inú Májẹ̀mú àtijọ́ àti Majẹmu titun, pẹ̀lú Ìwé Orin Dáfídì láàrin wọn. Apá kinni ní àwọn Iwé Luku, Ise awon Aposteli, Danieli, ati Jenesisi.