← Àwon ètò
Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú Joh 9

Johannu
Ojó Méwàá
Ètò kekere yìí yóò darí rè kojá lo si Ìhìnrere níbámu pẹ̀lú Jòhánù láti ìbẹ̀rẹ̀ títí dé òpin.

Ìhìnrere Johanu
21 Awọn ọjọ
Nínú ètò ẹsẹ̀-Bibeli-kan-lójúmọ́ yìí, ìwọ yóò bá Ọlọrun Alágbára pàdé – Aṣẹ̀dá ohun gbogbo – tó ní ìrísí ènìyàn, tí a bí láti mú ìgbàlà wá fún gbogbo ènìyàn, níbi gbogbo. Johanu ṣèrántí àwọn iṣẹ́ ìyanu, ẹ̀kọ́ àti àbápàdé ọ̀rẹ́ rẹ tímọ́tímọ́ jùlọ àti Olùgbàlà rẹ, Jesu. A pè ọ́ láti tẹ̀lé Jesu, pẹ̀lú, kí o sì gba ẹ̀bùn ìyè àìnípẹ̀kun Rẹ̀. YouVersion ni ó ṣàgbékalẹ̀ ètò yìí.