← Àwon ètò
Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú Isa 26:3

Lílò Àkókò Rẹ Fún Ọlọrun
Ọjọ́ Mẹ́rin
Ẹkọ bíbélì ọlọjọ merin lati ọwọ R.C. Sproul lórí lílo àkókò wà fún Ọlọrun. Ẹkọ bíbélì ikankàn npè wà láti máa gbé ní iwájú Ọlọrun, labẹ aṣẹ Ọlọrun, sí ògo Ọlọrun.

Wá Ọlọ́run Láàrin Rẹ̀
Ojó Méwàá
Ìrẹ̀wẹ̀sì. Àníyàn. Àwọn okùnfà àti àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ tí ó ro ni lára máa ń ní ipa tí ó ní agbára lórí ọpọlọ, ìmọ̀lára àtì ìgbé-ayé ẹ̀mí wa. Ní àwọn àkókò yìí, wíwá Ọlọ́run á dàbíi pé ó ṣòro tí kò sì já mọ́ ǹǹkan kan. Èròńgbà ètò kíkà yìí, "Wíwá Ọlọ́run Láàrin Rẹ̀" ni láti gbà ọ́ ní ìyànjú àti láti kọ́ ọ ní ọ̀nà tí o fi lè ṣe ìtara níwájú Ọlọ́run, kí o ba lè ní àlàáfíà Ọlọ́run nínú irú ipòkípò tí o lè wà.