Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú I. Joh 4:19

Wiwa ọna rẹ Pada si Ọlọhun
Ọjọ marun
Ṣe o n wa diẹ sii ninu igbesi aye? Fẹẹ diẹ sii jẹ gan kan npongbe lati pada si Olorun-nibikibi ti ibasepo rẹ pẹlu Ọlọrun ni bayi. Gbogbo wa ni iriri awọn ami-ami-tabi awakenings-bi a ti ri ọna wa pada si Ọlọhun. Irin ajo nipasẹ gbogbo awọn awakii yii ki o si sunmọ aaye laarin ibiti o wa ni bayi ati ibiti o fẹ lati wa. A fẹ lati wa Ọlọhun, o fẹ ani diẹ sii lati ri.

Ẹ̀jẹ́ Náà
Ọjọ́ mẹ́fà
Nínú Ètò Bíbélì Life.Church yí, àwọn l'ọkọ l'áya (tọkọtaya) mẹ́fà kọ nípa májẹ̀mú ìgbéyàwó tí wọn kò ní àǹfààní láti kà níwájú pẹpẹ. Àwọn májẹ̀mú ìpalémọ, oun-tó-ṣe-pàtàkì, ìlépa, àjọṣepọ̀, àìlábàwón, àdúrà ni májẹ̀mú tí ó máa ń mú ìgbéyàwó lọ létòletò kọjá àkókò adùn ayẹyẹ ìgbéyàwó. Bóyá o ti gbéyàwó tàbí o kò ì tí gbéyàwó, àkókò ti tó láti dá májẹ̀mú

Jésù: àsíá Ìṣẹ́gun wa
Ọjọ́ Méje
Nígbà tí a bá ń ṣe ayẹyẹ ajinde, à ń ṣe ayẹyẹ ìṣẹ́gun tí ó ga jùlọ nínú ìtàn. Nípa ikú àti ajinde Jésù', ó borí agbára ẹ̀ṣẹ̀ àti isà òkú títí láí, àti gbogbo ohun àbájáde wọn, ó sì yàn láti pín ìṣẹ́gun náà pẹ̀lú wa. Ní ọ̀sẹ̀ ayẹyẹ yii, jẹ́ kí á wọ inú díẹ̀ nínú àwọn odi agbára tí ó ṣẹ́gun, ṣe àṣàrò lóríi ìjà tí ó jà fún wa, kí o sì yìín gẹ́gẹ́bíi àsíá ìṣẹ́gun wa.

Ìgboyà
Ọ̀sẹ̀ kan
Kọ́ ohun tí Bíbélì sọ nípa ìgboyà. Ètò kíkà “Ìgboyà” rán àwọn onígbàgbọ́ létí ẹni tí wọ́n jẹ́ nínú Kristi àti nínú ìjọba Ọlọ́run. Nígbà tí a bá jẹ́ ti Ọlọrun, a ní òmìnira láti súnmọ́-On tààrà. Kà lẹ́ẹ̀kansi - tàbí bóyá fún ìgbà àkọ́kọ́ - àwọn ìdánilójú pé ipò rẹ nínú ìdílé Ọlọrun wà síbẹ̀.